ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌFỌ̀KÀNBALẸ̀ WÀ FÚN GBOGBO I.Y.P
Lára ànfààní Orílẹ̀-Èdè Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y) fún gbogbo àwa ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti D.R.Y, tí a sì fẹ́rẹ̀ẹ́ le pè ní kònkarí ànfààní orílẹ̀-èdè wa, ni pé, Ìfọ̀kànbalẹ̀ wà fún gbogbo I.Y.P ní D.R.Y. Gẹ́gẹ́bí Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ṣe máa ńsọ, Àlàkalẹ̀ tí Olódùmarè gbé fún […]