Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌKÌLỌ̀ FÚN GBOGBO Ẹ̀YIN ÀGBẸ̀

Ẹ má ṣe gba irúgbìn GMO lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni, ọ̀nà míràn láti pa àwa aláwọ̀ dúdú run ni, àìsàn oríṣiríṣi ni irúgbìn yí yóò fà sí àgọ́ ara ẹnití ó bá jẹẹ́, bẹ́ẹ̀ sì ni ẹni náà kò ní leè bí ọmọ mọ́, àti wípé, ilẹ̀ tí wọ́n bá gbin irúgbìn yí sí yóò di aṣálẹ̀ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN ÒYÌNBÓ KAN LÁTI ORÍLẸ̀ ÈDÈ RUSSIA LỌ SÍ ÀJÀÒKÚTA

Nínú ìròyìn kan tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni a ti gbọ́ wípé àwọn ọnímọ̀-ẹ̀rọ bíi mẹ́tàlélógún láti orílẹ̀ èdè Russia ni  wọ́n ti gúnlẹ̀ bàgẹ̀ báyìí o sí ilé iṣẹ́ Àjàòkúta, níbi tí agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà npè ní ìpínlẹ̀ Kogi, ṣùgbọ́n tí apá kan rẹ̀ jẹ́ ti Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN ÌKÀ ṢE ABURÚ FÚN ỌLỌ́PỌLỌ PÍPÉ !

Maxwell ni orúkọ ọkùnrin náà, ní ìlú Zimbabwe, ẹni tí Olódùmarè jogún làákàyè fún ní ti ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ ẹ̀rọ. Ìròhìn lórí ayélujára fi tó wa létí pé Maxwell ti ṣe oríṣiríṣi nkan bí ẹ̀rọ tó ngbé agbára iná mọ̀nọ̀mọ́ná jáde láì lo wáyà, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, ṣùgbọ́n nísiìyí, Maxwell wà ní ìlé-ìwòsàn, tìtorí àwọn tí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌMỌ BÌNÍ SỌ BÍ NÀÌJÍRÍÀ ṢE WÁYÉ

Ọmọ Bìní kan lórí ẹ̀rọ ayélujára ló ṣe àlàyé bí ibi tí wọ́n npè ní Nàíjíríà kò ṣe jẹ́ orílẹ̀-èdè, àti pé kíkó tí wọ́n kó Nàìjíríà jọ, gẹ́gẹ́bí ilé-iṣẹ́ ìdókòòwò ni – Royal Niger Company, èyí tí ó di Unilever lóni. Èyí fi hàn wá, gedegbe, bí ó ti ṣe pàtàkì kí á wádi […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌMỌ YORÙBÁ, Ẹ MÁṢE F’Ẹ̀MÍ ṢÒFÒ

Ìròhìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ lórí ẹ̀rọ ayélujára sọ pé, lọ́wọ́lọ́wọ́ báyi, àwọn ológun ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì npè fún àwọn ọmọ ìlú àjọṣepọ̀-oko-ẹrú wọn (Commonwealth Citizens) láti wá jẹ́ Ọmọ-Ogun Gẹ̀ẹ́sì! Ẹ má ṣe yà sí’bẹ̀ o! Ìròhìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ sọ pé wọ́n nwá àwọn tí wọ́n máa kó lọ ja ogun […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

OLÓRÍ NÍ JAPAN TỌRỌ ÀFORÍJÌ

Ìròhìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ sọ pé olórí kan ní ìlú Japan ti tọrọ àforíjì lọ́wọ́ àwọn tó kọ̀ pé àwọn ò ní gba abẹ́rẹ́-àjẹsára covid, látàrí pé àwọn mọ̀ pé wọ́n fẹ́ fi ṣekúpa’ni ni. Ó ní, “ẹ̀yin tí ẹ kọ̀ láti gba abẹ́rẹ́ àjẹsára yẹn, ẹ ti jàre mi o, Òótọ́ ni […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Àǹfààní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá: Iṣẹ́ Ṣíṣe

Yorùbá bọ̀, wọ́n ní, àgbàlagbà tó bá fàárọ̀ ṣeré, yóò fi ọjọ́ alẹ́ gbàárù, àti pé ìgúnpá nì’ye kan ẹni, àwọn náà ni wọ́n tún máa ń p’òwe wípé ìdí iṣẹ́ ẹni la tií mọ’ni lọ́lẹ. Ìdí tí àwọn òwe wọ̀nyí fi wáyé ni wípé, ìran Yorùbá fẹ́ràn láti máa tẹpá mọ́’ṣẹ́ púpọ̀, Yorùbá kò […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

BILL GATES KA ARA RẸ̀ SÍ OLÓDÙMARÈ

Ìròhìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ lórí ẹ̀rọ Ayélujára, ni oníròhìn, Tucker Carlson, ti Ilé-Isẹ́-Ìròhìn FOX NEWS ti sọ pé, Ìrànṣẹ́-Àṣìtáánì, Bill Gates, kò ka ara rẹ̀ sí ènìyàn o! Nṣe ló ka ara rẹ̀ sí Ẹlẹ́da, àti pé àkóso àgbáyé yí wà lọ́wọ́ òun. Ṣé ìdí tí a fi nsọ eléyi fún wa ni, […]

Read more
Say no to GMO foods in yoruba

ÀWỌN “ALÁGBAYÉ” FẸ́ GBA AYÉ !

Wọn ò kì nṣe Olódùmarè, ṣùgbọ́n wọ́n nhùwà bíi pé àwọn ni ó dá ayé! Àwọn ènìyàn máa npè wọ́n ní “Alágbayé” (globalists) nítorí pé àwọn ẹni ibi wọ̀nyí fẹ́ kí gbogbo àgbáyé ó wà lábẹ́ òrùlé kan ṣoṣo, kí ó sì jẹ́ pé àwọn ni ó máa máa ṣe àkóso òrùlé náà! Ẹ̀mí àṣìtáánì […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

MPOX àti Ìbálòpọ̀-Ọkùnrin-s’Ọkùnrin !

Ó ti wá “njọra” báyi o! – a ti nrí bí oríṣiríṣi ìwà-aburú tí àwọn tí ó pera wọn ní “Alágbáyé” (globalists) ngbé síta, bí ó ṣe so mọ́ ara wọn papọ̀! Wọ́n fẹ́ kí gbogbo ayé tẹríba fún òjé (irọ́) wọn nípa àrùn mpox tí ó jẹ́ pé àwọn ló ko síta; bẹ́ẹ̀ ni […]

Read more