HA ! ÈYÍ TÚN LÁGBÁRA Ò! APÀNÌYÀN NÍ ILẸ̀ GẸ̀Ẹ́SÌ
Ní agbègbè kan ní Manchester, ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, obìnrin kan ẹni ọdún mẹ́tàlélógójì, tí àwọn kan júwe gẹ́gẹ́bí ọmọ Orílẹ̀ èdè Uganda, ni ó ṣe àgbákò ikú òjijì láti ọwọ́ ọmọ bíbí inú rẹ̀ èyí tí ọjọ́ orí rẹ̀ kò ju ogún ọdún lọ. ìròyìn ọ̀hún tún tẹ̀síwájú wípé, lẹ́yìn tí ọ̀dọ́mọkùnrin yí gún ìyá rẹ̀ […]