KÒ SÍ ÌBÒJÚ W’Ẹ̀YÌN! IBRAHIM TRAORE LÓ SỌ BẸ́Ẹ̀
Ọ̀rọ̀ akin ati ìgboyà yí ló jáde láti ọ̀dọ̀ olórí Orílẹ̀ èdè Burkina Faso, Ọ̀gágun Ibrahim Traore, akíkanjú ọ̀dọ̀mọkùnrin tó fẹ́ràn àwọn ènìyàn rẹ tọkàn- tọkàn. Ọ̀rọ̀ akin náà jẹ́ eyi tí aṣojú Ọ̀gágun náà ṣe àgbékalè rẹ ni iwájú àwọn ìjọba àgbáyé (UN) ni ìlú New York. Àwọn kókó ọ̀rọ̀ rẹ sí ìjọba àgbáyé dá […]