• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

IMF TI YÁ’WÓ L’ỌWỌ́ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍA RÍ

Bóyá Fúlàní ni; bóyá inkan-kí’nkan tí ìbáà wù kó jẹ́, èyí tí ó pe’ra rẹ̀ ní Alhaji Abubakar Alhaji, tí ó jẹ́ mínisítà ètò ìṣúná ní agbésùnmọ̀mí nàìjíríà ní àkókò ìṣejọba shagari ní ìlú aríremáṣe nàìjíríà náà, sọ pé nṣe ni òun nsun ẹkún fún Nàìjíríà, l’oní, torí pé, ní ẹgbàá ọdún ó dín mẹ́rin-dín-l’ọgbọ̀n, […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ọ̀DỌ́BÌNRIN TÓ NÍ ÀÌSÀN JẸJẸRẸ

Ọ̀dọ́bìnrin kan ẹni ọdún méjìlélógún tó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ Fáṣítì ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, D.R.Y, èyí tí ìlú agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà ń fi ipá jẹ gàba lé lórí, ni a gbọ́ wípé ó ní àìsàn jẹjẹrẹ tí ó sì nílò mílíọ̀nù márùndínlógún náírà fún ìtọ́jú. Eléyi gba omijé lójú ẹni. Ó wá di dandan […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ILẸ̀ ỌLỌ́RÀÁ NI ILẸ̀ YORÙBÁ

Tí a bá rí ẹnikẹ́ni tó ń sọ wípé kíni àwa ìran Yorùbá máa jẹ bí a ṣe dá dúró gẹ́gẹ́ bíi orílẹ̀ èdè, a jẹ́ wípé irú ẹni bẹ́ẹ̀ ní ojú ṣùgbọ́n kò fi ríran.  Láìpẹ́ yìí ní a rí fọ́nrán arákùnrin kan tó ń ṣe àfihàn tòmátì tó kórè nínú oko, kìí ṣe […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ỌMỌ YORÙBÁ Ò TÚN ṢE ẸRÚ MỌ́

Nígbà gbogbo ní àwa ìran Yorùbá yóò máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Olódùmarè tó sí’jú àánú wò wá, tó rán ìyá onínúure sí wa láti tú wa sílẹ̀ kúrò nínú oko ẹrú, gẹ́gẹ́ bí màmá wa, ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla ṣe máa ń sọ fún wa wípé, ọmọ Yorùbá ò ní ti oko ẹrú kan bọ́ sí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌJỌBA GẸ̀Ẹ́SÌ GBÉ IṢẸ́ FÚN ÀWỌN NỌ́Ọ̀SÌ AṢEKÚPANI

Ìyàlẹ́nu ń lá ló jẹ́ láti rí ìròyìn kan  lórí ẹ̀rọ ayélujára wí pé, ìjọba Bìrìtìkó (Gẹ̀ẹ́sì) gba àwọn nọ́ọ̀sì agbanipa ní àkókò àìsàn Covid 19 tó gba’lé gba oko nígbà náà láti pa ọ̀pọ̀ àwọn tó ń gba ìtọ́jú fún àrùn náà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíọ̀nù àwọn aláìsàn Covid 19 yí ni wọ́n pa láì jẹ́ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌJỌBA AJẸGÀBA LÓ NFA IKÚ ÒJIJÌ

Ìjẹgàba àwọn ìkà agbèsùnmọ̀mí nàìjíríà ní Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá – D.R.Y) ti sọ ayé àwọn ènìyàn di idàkudà. Ìròyìn kan ló jáde lori àwọn aláwo kan, Alfa Yinusa Atikoko àti Wasiu Ajikanle tí wọn ká orí òkú  mérìndínlógún mọ lọwọ. Ìròyìn náà kò sọ pàtó ìlú tó jẹ́, […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ọ̀FỌ̀ ṢẸ̀ NÍPASẸ̀ ÌJẸGÀBA AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ

Ìbá ṣe wípé agbésùnmọ̀mí nàìjíríà kò fi ipá dúró lórí ilẹ̀ wa, Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), a  bá má ti rí ìdojúkọ ìpànìyàn àti ìjínigbé tí àwọn Fulani ń ṣe ní ilẹ̀ Yorùbá. Ọ̀rọ̀ yí wá nítorí ìròyìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́, nípa ìlú Igbó-Ọrà, tí a rí fọ́nrá àwọn obìnrín méjì […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌDÀGBÀSÓKÈ ÌGBÈRÍKO

Ìdàgbàsókè gbogbo ilẹ̀ Yorùbá ni ó jẹ ìjọba Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) lógún, lábẹ́ ìṣàkóso Àlàkalẹ̀ tí Olódùmarè gbé fún Ìran Yorùbá, nípasẹ̀ Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá. Gẹ́gẹ́bí Màmá wa ti sọ, gbogbo ilẹ̀ Yorùbá ni ó máa ní ìdàgbàsókè àti ìgbá’yé gbádùn. Èyí tó jẹ́ pé […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌWÀ ÌTÀNJẸ ÀWỌN AMÚNISÌN

Nínú fọ́nrán kan lati ri gbọ́ wípé, ọkọ̀ tó ń lo iná mọ̀nàmọ́ná ti wà láti ayégbọ́ngan ṣùgbọ́n, nítorípé àwọn amúnisìn yí fẹ́ ma jẹ èrè gọbọi lórí epo rọ̀bì àti epo bẹtiróòlù pẹ̀lú ìwà ìjẹgàba wọn lórí àwọn orílẹ̀-èdè míràn ni àwọn aláwọ̀-ẹlẹ́dẹ̀ ṣe fi irú nǹkan bayi pamọ́ fún àgbáyé. Bí àwọn apanijayé yìí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌSỌKÚSỌ LẸ́NU WÈRÈ ÒGÚNWÙSÌ !

Nígbà tí a bá sọ pé kò sí nǹkan tó ń jẹ́ ọba ní Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), òótọ́ àti òdodo ni; kí ẹnikẹ́ni má sì ṣe lòdì sí ọ̀rọ̀ yí, kò sí ọba ní D.R.Y. Kí á sì rántí pé ìjọba D.R.Y ti bẹ̀rẹ̀. Nítorí èyí, ó jẹ́ ọ̀ràn-dídá fún ẹnikẹ́ni láti […]

Read more