Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: OÚNJẸ TÓ DÁRA

Ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), ìgbádùn tí yóò wà fún wa kò lóǹkà, àìríjẹ ti di ohun ìgbàgbé ní ilẹ̀ Yorùbá, oúnjẹ tó dára ní a óò máa jẹ́, nítorí pé ìjọba D.R.Y kò ní fàyè gba ayédèrú oúnjẹ GMO tàbí lílo èròjà tó leè ṣe àkóbá fún […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

KÒ SÌ ÀYÈ FÚN ÀJÈJÌ LÁTI DÍJE FÚN IPÒ

Ètò ìṣèlú ní Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) kò ní fí àyè gba àjèjì láti díje fún ìpò kankan nínú ìdìbò orílẹ̀ èdè Yorùbá. Màmá wa Olóyè Ìyá Ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla fìdí ọ̀rọ̀ yí múlẹ lára àlàyé wọn nípa ètò ìdìbò wa, bí ó ti wà nínú àlàkalẹ̀ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÈTÒ FÚN ÀWỌN ARÚGBÓ

A dúpẹ́ lọ́wọ́ Olódùmarè fún àánú rẹ̀ lórí ayé ìran Yorùbá, Tó dá ìgbà ọ̀tun padà fún àwa ọmọ Aládé nípasẹ̀ màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla Tó fi iṣẹ́ náà rán sí àwa ènìyàn rẹ̀ pẹ̀lú àlàkalẹ̀ ètò tó fi ti Yorùbá ṣe àkọ́kọ́ lẹ́yìn Olódùmarè tó sì kún fún ìgbá’yé gbá’dùn lorísìírísìí. Ṣé […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN ỌBA KÒ WÚLÒ FÚN WA

Láti ìgbà ìwáṣẹ̀ ní àwọn ọba ilẹ̀ Yorùbá kò ti ní ànfàní kankan ti wọ́n nṣe fún ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, gẹ́gẹ́bí ìwádìí ìjìnlè tí òrìṣà òmìnira ilẹ̀ Yorùbá, màmá wa Olóyè Ìyá Ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla ṣe lóri ipá tí àwọn ọba yí kò nínú ayé ọmọ Aládé, ìyà àti ìrẹ́jẹ ni ipò ọba jẹ́ fún […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌKÌLỌ̀ FÚN I.Y.P NÍPA ÈTÒ Ẹ̀KỌ́ !

Òrọ̀ ti jáde o! Àṣẹ sì ti gùn-ún, nípa ilé-ìwé ní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) lọ́wọ́-lọ́wọ́ báyi. Ṣé tẹ́lẹ̀ ni a tilẹ̀ ti mọ̀ pé, ní Ọjọ́ Kéjìlá, Oṣù Igbe ẹgbàá-ọdún ó lé mẹ́rin-lé-lógún, ni Olórí Aṣojú Ètò Ìmòjútó Ará-Ìlú D.R.Y, Bàbá wa, Mobọ́lájí Ọláwálé Akinọlá Ọmọ́kọ́rẹ́, ti […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌGBÁDÙN ỌRỌ̀ LỌ́PỌ̀LỌPỌ̀

Olódùmarè fi ọrọ̀ rẹpẹtẹ dá ilẹ̀ Yorùbá lọ́lá, Ó fún wa ní ilẹ̀ ọlọ́ràá tó nṣe àtìlẹyìn fún oríṣìíríṣìí ohùn ọ̀gbīn láti so dáradára àti lọ́pọ̀lọ́pọ̀, ní ìgbà ojo, ẹ̀rùn, ooru, òtútù ati bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀, nítorínáà, a ó ní ànító oúnjẹ àti àjẹṣẹ́kù. Ní àfikùn, Olódùmarè fún wa ní àwọn ènìyàn tó pọ̀, tó sì ní […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀGBÉKALẸ̀ ÀWỌN AMÚNISÌN

Lẹ́hìn tí àwọn amúnisìn ti ríi dájú pé, àwọn ti ṣẹ́gun àwọn Ọba ilẹ̀ Yorùbá ni wọn wá ṣe àgbékalẹ̀ láti da orílẹ̀ èdè míràn papọ̀ mọ́ orílẹ̀-èdè Yorùbá fún ìwúlò orílẹ̀-èdè àti ẹ̀yà ti wọn.  Lára àwọn àgbékalẹ̀ ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà yìí dálé lóríí ìfipá jẹ gàba, ìmúnisìn, ìdókoòwò pẹ̀lú ẹ̀tàn. Látàrí ìwà ìkà […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: D.R.Y KÒ NÍ TỌRỌ

Tí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa orílẹ̀ èdè tí Olódùmarè kẹ́ pẹ̀lú àlùmọ́ọ́nì lorísìírísìí ní àgbáyé, orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y) jẹ́ ọ̀kan gbòógì. Bí a ṣe ní àlùmọ́ọ́nì ti ilẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn omi lorísìírísìí tó leè máa mú owó wọlé sí orílẹ̀ èdè wa. Ilẹ̀ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌPÌLẸ̀ KẸ́TA

Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, máa nsọ àwọn gbólóhùn ọ̀rọ̀ kan – wọ́n máa nsọ pé ìpìlẹ̀ kẹ́ta, fún Ìran Yorùbá, ni iṣẹ́ tí a nṣe lọ́wọ́lọ́wọ́ yí, àti pé, ìpìlẹ̀ eléyi, kò gbọdọ̀ wó láíláí nítorí ìrìn-àjò ẹ̀mí ni Democratic Republic of the Yorùbá (D.R.Y).  Nítorí náà, kí a jẹ́ kí ìrìn-àjò náà kí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌBA ILẸ̀ YORÙBÁ LÁBẸ́ ÀWỌN AMÚNISÌN

Lẹ́yìn tí àwọn òyìnbó amúnisìn ti gbàkóso ìṣèjọba ilẹ̀ Yorùbá tán, tí wọ́n sọ ọmọ Yorùbá sí oko ẹrú, àwọn ọba yí ṣì wà ní ipò ọba láìsí agbára tàbí àṣẹ láti ṣe ìjọba mọ́, ṣùgbọ́n àwọn amúnisìn fí wọ́n síbẹ̀ gégébí olórí ẹrú tí wọ́n ńlò láti ṣe àkóso ètò ìmúnisìn àti ìmúnilẹ́rú. Iṣẹ́ […]

Read more