Tí o bá fẹ́ sọ ẹ̀yàk’ẹyà di ẹrú, gba èdè àti ìtàn wọn – Wendall Donelson
Arákùnrin kan tí a mọ orúkọ rẹ̀ sí Wendall Kēñõ Donelson, l’orí ẹ̀rọ ayélujá’ra Facebook, l’o sọ o, wípé tí ẹnik’ẹ́ni bá fẹ́ sọ àwọn míràn di ẹrú, ó ní ohun mẹ́ta ni o ní l’ati gbà l’ọwọ́ wọn o, kí wọ́n tó lè di ẹrú l’abẹ́ rẹ. Èkínní, ó ní kí o gba Ìtàn […]