• Oríkò Ilé-Iṣẹ́, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌPÍNLẸ̀ ÒGÙN NJẸ CHINA LÓWÓ, NI CHINA BÁ GBA ỌKỌ̀ BÀLÚÙ NÀÌJÍRÍÀ! Òótọ́ tàbí Eré?

Ní ẹgbàá ọdún ó lé méje, lábẹ́ Àkóso Gbenga Daniel, gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn, nígbà náà tí a ṣì wà nínú Nàìjíríà, ni a gbọ́ pé àdéhùn kan wáyé, láarín ìpínlẹ̀ Ògùn àti ilé-iṣẹ́ Sháínà kan tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Zhongshan, pé kí ilé-iṣẹ́ yí ó kọ́ gbàgede Ìṣòwò àìlówó-orí (Free Trade Zone), èyí tí kárà-kátà […]

Read more
Chief Mrs Modupe Onitire Abiola - Democratic Republic of the Yoruba

Ẹ WO IṢẸ́ ÌYANU OLÓDÙMARÈ: MÀMÁ WA SỌ PÉ Ọ̀DỌ́ LÓ MA ṢÉ, Ó PÉ OṢÙ MẸ́RIN GÉÉRÉ-GÉ TÍ ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BẸ̀RẸ̀ ÌJỌBA NI A ṢE ÀYÁJỌ́ ỌJỌ́ ÀWỌN Ọ̀DỌ́

Ohun míràn á sì ṣẹlẹ̀, ní wẹ́rẹ́, á wá ṣeni ní Hàà, nígbàtí a bá wo’lẹ̀, tí a wẹnu ọkọ́! Ní ọjọ́ kéjìlá, oṣù ògún, lọ́dọọdún, ni Àyájọ́ Ọjọ́ Àwọn Ọ̀dọ́, tí a máa nránti ipò tí Àwọn Ọ̀dọ́ wà, káàkiri àgbáyé, àti kíni ó yẹ kí àwùjọ ó ṣe, láti gbé ipò, ìjẹ́-ọmọ-ènìyàn, àti […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

BURKÍNÁ FASÒ GBÉ ÌGBÉSẸ̀ FÚN OHUN ÀMÚṢAGBÁRA

Orílẹ̀-Èdè Burkíná Fasò ti pinu láti dá ilé-iṣẹ́ tí ó máa gbé agbára jáde láti inú hóró-àyíká, èyí tí wọ́n pè ní “àtomic energy,” látàrí kí wọ́n máṣe gbẹ́kẹ̀lé ará-ìta fún ohun àmúṣagbára, gẹ́gẹ́bí agbára iná mọ̀nọ̀mọ́nọ́, fún àpẹrẹ; àti fún ìdàgbàsókè ìlú wọn ní dídá ìlé-iṣẹ́ sílẹ̀, àtí kí gbogbo agbègbè ìlú wọn le […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌJÀMBÁ ỌKỌ̀ NÍ ÌWÒRÒKÓ-ÈKÌTÌ

Fọ́nrọ́n kan tí a rí ṣe àfihàn ọkọ̀-àjàgbé kan tí wọ́n kọ “Dangote” sí lára, tó ṣubú forí-dólẹ̀ ní ìlú Ìwòròkó-Èkìti, Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, níbi tí aṣiwèrè Oyèbánjí, gómìnà Nàìjíríà ti njẹgàba sórí ilẹ̀ ọmọ Yorùbá, tí ó sì jẹ́ pé a ò sí lára Nàìjíríà mọ́ láti ogúnjọ́ oṣù bélú, ẹgbàá ọdún […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌJẸGÀBA ÌLÚ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ LÓRÍ DEMOCRATIC REPUBLIC OF THE YORUBA, Ó TÓ GẸ́Ẹ́ !

Ní ìpínlẹ̀ Ìbàdàn, ní agbègbè Amúlóko, ní Orílẹ̀-Èdè Democratic Republic of the Yoruba, ni ọwọ́ ti tẹ ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Musa tí ó sì ti ń kà bòòròbò báyìí látàrí pé wọ́n ká orí ènìyàn mọ́ọ lọ́wọ́. Gégébí àlàyé ọkùnrin náà nígbàtí ó ń jẹ́wọ́ ìwà búburú yìí, ó ní ìgbà […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÈTÒ AMÚLUDÙN, NÍ TI ORIN KÍKỌ

Lára ànfààní orílẹ̀-èdè wa, Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, èyí tí a tún mọ̀ sí Yoruba Kingdom, Yoruba Nation, Yoruba Land, àti Yoruba Country; ni Ètò Amúludùn, pàtàkì ní ti Orin Kíkọ. Orin Kíkọ jẹ́ ohun àtayébáyé ní ilẹ̀ Yorùbá; gẹ́gẹ́bí Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá dẹ̀ ṣe sọ, a máa gbé ọ̀rọ̀ orin-kíkọ lárugẹ; […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

SEYI MAKINDE, Ẹ̀ṢẸ̀ RẸ̀ Ń PỌ̀ SÍ LÓJOOJÚMỌ́

Seyi Makinde, àti gbogbo ẹ̀yin tí ẹ pera yín ní àgbà, àgbà òfò, ní ilẹ̀ Yorùbá, pẹ̀lú ẹ̀yin tí ẹ pe ara yín lọ́ba, ní ilẹ̀ Yorùbá, ṣùgbọ́n tí ẹ lọ ńrán àwọn èèyàn sí awon ọmọ Yorùbá tí ẹ jí gbé, pẹ̀lú àwọn ọmọ-ogun Orílẹ̀-Èdè wa, Democratic Republic of the Yoruba, tí ẹ jígbé, […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÒṢÌṢẸ́ PA Ọ̀GÁ WỌN NÍ ÌLÚ ÀKÚRẸ.. HÀÀ!

Àwọn òṣìṣẹ́ méjì kan, àwakọ̀ àti olùrànlọ́wọ́-iṣẹ́, ni a gbọ́ pé wọ́n kó àwọn míràn mọ́ra, tí ó jẹ́ pé wọ́n wá ṣekú pa ọ̀gá wọn, Abilékọ Ọlákúnbi Adene, tí ó jẹ́ gbajúmọ̀ olónjẹ ní ìlú Àkúrẹ́, ní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá wa yí.  Ọ̀rọ̀ gbogbo lórí alábahun ni ọ̀rọ̀ yí jẹ́ o – […]

Read more