ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÈTÒ ÌWÒSÀN
Oore tí Olódùmarè ṣe fún ìran Yorùbá yí, aò ní gbàgbé láéláé. Gẹ́gẹ́ bí màmá wa, ìyá Òmìnira Yorùbá, Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá Ààfin) ṣe máa ń sọ pé, à ò gbọ́dọ̀ gbàgbé oore tí Olódùmarè ṣe yí, nígbà gbogbo ni kí a máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run wa fún àánú tí a rí gbà. Ọmọ […]