Àbí ẹ̀ ò rí nǹkan bí, ẹ wo ọ̀dọ́ Ààrẹ Bassirou Fàyè ti òrílẹ̀ èdè Senegal tí ó ń fẹ́ ire fáwọn èèyàn rẹ̀, nígbà tí ìkà ti Naijiria, ni’bi tí a ti jáde báyìí ń wá ìnira fún àwọn ìran tirẹ̀, ìyẹn tó bá jẹ́ pé ìran Yorùbá ló jẹ́ ní tòótọ́ bí ó ṣe ń pe ara rẹ̀ o.
Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá l’a nkójọ pọ̀ gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí. Pín sórí agbàgbé X (Twitter)Ṣé ẹ rí ìdí tí ẹ má fi mọ̀ pé inú ìgbádùn ni àwa omo IYP (ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá) wà.
Àti ìdí tí àwa ojúlówó ọmọ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá ṣe ní ìrètí ògo ọjọ́ ọ̀la tí ó fi ọkàn balẹ̀ làti owó àwọn odò wá lórí ilẹ̀ DRY, ilè Olómìnira wa, àwọn odo wá lè ṣe, wón má ṣeé , gbogbo wa là má jèrè ilẹ̀ Democratic Republic of the Yorùbá ní agbára Olódùmarè. Ire o.
Ka Ìròyìn:Ohun Nlá Ṣẹlẹ̀ Nílẹ̀ Yorùbá Ní Ọjọ́ Kéjìlá, Oṣù Kẹ́rin, Ọdún 2024!
Ka Ìròyìn: Bill Gates: Ìránṣẹ́ Apànìyàn Tí Àṣìtáánì Nlo Lati Ṣe’Jàǹbá Fun Aláwọ̀dúdú