ÀṢÍRÍ ÀWỌN AJẸGÀBA TI TÚ O!
Màmá wa, ÌRÁNṢẸ́ OLÓDÙMARÈ sí ìran Yorùbá, Màmá, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, tú àṣírí àwọn afipá jẹgàba tó wà lórí ilẹ̀ wa, pẹ̀lú àwọn alábaṣiṣẹ́-pọ̀ wọn – àwọn ọ̀bàyéjẹ́ tí wọ́n pera wọn lọ́ba. Màmá wa MOA jẹ́ kí á mọ̀ nínú ọ̀rọ̀ tí wọ́n bá wa sọ lórí amóhùnmáwòrán orílẹ̀-èdè wa, iypdry TV, pé àwọn ajẹgàba […]