ÌDÀGBÀSÓKÈ ORÍLẸ̀ ÈDÈ BURKINA FASO
Ìjọba orílẹ̀ èdè Burkina Faso ṣe’lérí iná mọ̀nàmọ́ná tó dúró déédéé fún àwọn ọmọ ìlú rẹ̀, wọ́n sì sọ pé ó ṣe-é-ṣe kí eléyi wáyé nípasẹ̀ àgbékalẹ̀ irinṣẹ́ alágbára tí wọn ń gbèrò láti s’ àgbékalẹ̀ rẹ̀. Ààrẹ Traore sọ pé èyí ṣe pàtàkì nítorí pé àwọn wà ní ààringbùngbùn ìwọ̀-oòrùn Afrika Láti ìgbà tí Ibrahim […]