ÌDÍ TÍ A FI ṢE ÌGBÀPADÀ
Nínú ìrìn àjò wa sí òmìnira, ìgbésẹ ìgbàpadà tí a ṣe jẹ́ pàtàkì fún àwọn ìdí tí màmá wa, òrìṣà òmìnira ilẹ̀ Yorùbá, Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá Ààfin) ṣe àlàyé rẹ̀ fún wa nínú ọ̀rọ̀ tí wọ́n fi kí àwa ojúlówó ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ní ìgbà àjọyọ̀ ọdún kejì Ifitónilétí gbígba […]