ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌGBÁDÙN FUN ÀWỌN ONÍṢẸ́ ỌWỌ́ ÀTI ÒNTÀJÀ
Ní Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y), ìrọ̀rùn ni àwọn oníṣẹ́ ọwọ́ àti òntàjà yíó ma fi ṣiṣẹ́ wọn nítorí kò ní sí ìyọnu fún wọn. Nínú àlàyé màmá wa Modúpẹ́ọlá Onitiri-Abiọla, (Olóyè Ìyá Ààfin) lórí àlàkalẹ̀ ètò ìṣàkóso wa, D.R.Y kò ní fi àyè gba ẹgbẹ́ ọlọ́jà tàbí […]