• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y

ORIN ÀSÍÁ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ (D.R.Y) [PDF & MP3]

-

Declaration

ORIN ÀSÍÁ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ (D.R.Y) [PDF & MP3]

Iṣẹ́ wa fún ‘lẹ̀ wa,
Fún Ilẹ̀ ìbí wa,
K’á gbega, k’á gbega,
K’á gbega f’aiyé rí.

Ìgbàgbó wa ni ‘pé,
B’a ti b’ẹrú l’a b’ọmọ
K’á ṣ’iṣẹ́, k’á ṣ’iṣẹ́
K’a ṣ’iṣẹ́ k’a jọ là.

Ìsọ̀kan àt’òmìnira,
Ni ẹ jẹ́ k’á mã lépa, ‘Tẹ̀síwájú f’ọpọ̀ ire
Àt’ohun t’ó dára.

Ọmọ Òduà dìde,
Bọ́ sí’pò ẹ̀tọ́ rẹ,
Ìwọ ni ìmọ́lẹ̀
Ògo Adúláwọ̀.

Attachments

  • DEMOCRATIC_REPUBLIC_OF_THE_YORUBA-national-anthem.mp3 mp3 (2579kb)
  • DEMOCRATIC_REPUBLIC_OF_THE_YORUBA-national-anthem-2.pdf pdf (1057kb)