- Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
Orílẹ̀-Èdè Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ Orílè-èdè Tuntun Olómìnira lati ọjọ Jimọ, ọjọ Kejìlá ti Oṣu Kẹrin (Ìgbé) ọdún 2024. Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ́ 17th ní Iwọ-oòrùn Áfíríkà, Orílẹ̀-èdè 55th ní Áfíríkà, ati Orílẹ̀-èdè Tuntun ni Àgbáyé. D.R.Y jáde kúrò, o sí farahàn ni àlàáfíà nipasẹ ìwé àdéhùn Àjọ Àgbáyé (UN) lorí ẹtọ ọmọ ènìyàn, àwọn ẹtọ ìpinnu-lọkan ara ẹnì fún idà dúró gẹgẹ bi orílè-èdè.
Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (D.R Yorùbá)
© Copyright 2024 Nípasẹ̀ Ìjọba Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá