ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÈTÒ FÚN I.Y.P
Ìbànújẹ́ kò sí fún ẹnikẹ́ni mọ́ ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) pàápàá jùlọ àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) nítorí pé, àlàkalẹ̀ ètò ìṣàkóso tí Olódùmarè gbé fún Màmá wa, ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla kò yọ ẹnikẹ́ni sílẹ̀. Gbogbo àwọn àlùmọ́ọ́nì tí Olódùmarè fi […]
OLÓDÙMARÈ TI KÓ ÌRAN YORÙBÁ YỌ
Ọpẹ́lọpẹ́ Olódùmarè tó wípé ní déédéé ìgbà yí àti ní déédéé àsìkò yí ni kí àwa ìran Yorùbá padà sílé, tó wá gbé ẹni bí ọkàn Rẹ̀ dìde láti jẹ́ iṣẹ́ náà. Màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla, ìyá ìran Yorùbá, kí àánú àti ààbò Olódùmarè máa bá a yín gbé nígbà gbogbo. Gẹ́gẹ́bí ọ̀rọ̀ […]
ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌMỌ́TÓTÓ AGBÈGBÈ
Bí a ò kú, ìṣe ò tán Láìsí ìmọ́tótó agbègbè àti àyíká wa, nílé, lóko, lọ́nà ìrìn-àjò, kò sí bí a ṣe máa káwọ́ àrùn tàbí àìsàn. Èyí ló fi dá’ni lójú pé, orílẹ̀-èdè D.R.Y kò ní fi àyè gba ẹnikẹ́ni láti hu ìwà ọ̀bùn tàbí aláìbìkítà fún agbègbè àti àyíká wa. Ìṣàkóso D.R.Y ní […]
KÒ SÍ ÀWÁWÍ
Màmá Ìran Yorùbá, Ẹni tí Olódùmarè rán sí wa láti ṣe iṣẹ́ ìgbàlà Òmìnira àti ìdándè fún ìlọsíwájú àti Ìdàgbàsókè ọmọ-Yorùbá, Ìyá wa, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti ṣe ìkìlọ̀ tó lágbára fún gbogbo àwa ojúlówó ọmọ-Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yorùbá (D.R.Y). Wọ́n ní kò sí àwáwí kankan fún I.Y.P […]
ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: AṢỌ ÌBÍLẸ̀ YORÙBÁ
Ní gbogbo ìgbà ni àwa ìran Yorùbá yóò máa fi ọkàn ìmoore wa hàn sí Ọlọ́run Olódùmarè fún ìyanu ńlá tó ṣe fún wa nípasẹ̀ màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla tí Olódùmarè fi iṣẹ́ ìtúsílẹ̀ àwa ọmọ Aládé rán. Gẹ́gẹ́ bí màmá wa MOA ṣe máa ń sọ fún wa wípé, àlàkalẹ̀ ètò ìṣàkóso […]
D.R.Y JẸ́ ÀWÒKỌ́ṢE RERE L’ÁFRÍKÀ
Nínú àwọn àlàkalẹ̀ ètò ìṣàkóso orílẹ̀ èdè D.R.Y tí Olódùmarè jogún fún Màmá wa ìyá ààfin Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá nípa ọ̀nà tí ìdàgbàsókè máa ṣe débá orílẹ̀ èdè wa, ni àwọn oríṣìríṣì orílẹ̀ èdè míràn ti ńwo àwòkọ́ṣe rere àwọn àlàkalẹ̀ yìí. Lára àwọn àlàkalẹ̀ ìṣàkóso tó wà ní ilẹ̀ wa ni èdè wa, èdè Yorùbá […]
ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÈDÈ WA
Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) èdè Yorùbá nìkan ni èdè ìbánisọ̀rọ̀ àti ìkọsílẹ̀ fún ohun tí a fẹ́ ṣe ní ilé iṣẹ́, ilé ẹ̀kọ́, ilé ìtajà, gbogbo ohun tí ó jẹ́ ìgbé-ìlú. Màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla ti jẹ́ ká mọ pàtàkì sísọ èdè abínibí wa […]
ỌMỌ YORÙBÁ ÀGBÁYÉ Ń RETÍ WA
Akí gbogbo àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) kú oríire fún àṣeyọrí tí Olódùmarè lo màmá wa ìyá ìran Yorùbá Ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla láti ṣe fún ìran Yorùbá. Ní ogúnjọ́ oṣù Bélú ẹgbàáọdúnóléméjìlélógún Olódùmarè lo màmá wa MOA […]
I.Y.P KÒ TÚN ṢE ẸRÚ MỌ́
Gbogbo àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), ẹ jẹ́ kí a máa fi ọpẹ́ fún Olódùmarè fún ìyanu tó ṣe fún wa. Ní ojoojúmọ́ ni kí a máa fi ọpẹ́ fún- un, kí a sì máa yìn- ín. Gẹ́gẹ́ […]
ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: Ẹ̀YÁWÓ TÍ KÒ NÍ ÈLÉ
Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, ètò ẹ̀yáwó tí kò ní èlé yóò wà fún gbogbo ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá (I.Y.P). Nítorí èyí kí a ma jó kí a sì ma yọ̀. Nígbà gbogbo ní àwa Indigenous Yorùbá People (I.Y.P) a ó máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ẹlẹ́dàá wa tó rántí wa sí rere ní déédéé ìgbà […]