Ni Ìgbàgbọ́ Nínú Aráa rẹ!

je ki àgbáyé
rí ogo rẹ

Awọn eto ìdàgbàsókè ere-ìdárayá fun àwọn ọdọ ti yio ma mu ìdàgbàsókè ba gbogbo orílẹ̀ èdè Yoruba.

Ere Bọọlu Afẹsẹgba

Kí kópa nínù ere ìdárayá ti bọọlu afẹsẹgba ni orílẹ̀ èdè wa - ọlọrẹ sọrẹ, ìfé ti ilẹ̀ adúláwò, àti ìfé ti àgbáyé.

Bọọlu Afọwọgba

Kí kópa nínù ere ìdárayá ti Bọọlu Afọwọgba ni orílẹ̀ èdè wa - ọlọrẹ sọrẹ, ìfé ti ilẹ̀ adúláwò, àti ìfé ti àgbáyé.

Tẹnisi Orí Tabili

Kí kópa nínù ere ìdárayá ti Tẹnisi Orí Tabili ni orílẹ̀ èdè wa - ọlọrẹ sọrẹ, ìfé ti ilẹ̀ adúláwò, àti ìfé ti àgbáyé.

The Democratic Republic of the Yoruba Official Information Portal

Sporting Activities

Promoting Healthy
Lifestyle

Ìjọba ti ṣe ètò lorisirisi silẹ fun gbogbo ọdọ ilẹ Yorùbá ti wọn nifẹ si ere ìdárayá.

Àgbékalẹ̀ ẹtọ ìṣejọba ti Olómìnira tiwantiwa tí a mọ sí Blueprint ti Olódùmarè fúnra rẹ gbe fun mama wa Modupeola Onitiri-Abiola, ni ko yọ ọmọdé tàbí àgbà silẹ nipapajulọ, eyi to niṣe lori ọrọ ìdárayá.

Erońgba wa ni láti múra sílẹ̀ fun àwọn ere ìdárayá ti o ma n wáyé lọdọọdún káàkiri àgbáyé láti ja’we olubori, láti gba ife ẹyẹ, ati láti fihàn fún gbogbo àgbáyé pé Ọmọ-Aládé ni awa ọmọ orílẹ èdè Yorùbá. Orí ni wa, así gbọdọ je ki àgbáyé mọ!

Ìwọ ti o ba ni’fẹ si ere ìdárayá, f’ọkàn balẹ, ko sí oju ìṣáájú ni orílẹ èdè ti Yorùbá, bẹẹni kò sì pe mi o mọ eniyàn lókè.

Bẹrẹ si ńṣe àwárí ogo rẹ nítorí pé láìpẹ́ yi, ìjọba ma bẹrẹ ìṣe.

Ere ìdárayá tí Kẹkẹ

Kí kópa nínù ere ìdárayá tó ní ka fi Kẹkẹ sáré ni orílẹ̀ èdè wa - ọlọrẹ sọrẹ, ìfé ti ilẹ̀ adúláwò, àti ìfé ti àgbáyé.

Bọọlu Afọwọgba

Kí kópa nínù ere ìdárayá ti Bọọlu Afọwọgba ni orílẹ̀ èdè wa - ọlọrẹ sọrẹ, ìfé ti ilẹ̀ adúláwò, àti ìfé ti àgbáyé.

Ere Bọọlu Afẹsẹgba

Kí kópa nínù ere ìdárayá ti bọọlu afẹsẹgba ni orílẹ̀ èdè wa - ọlọrẹ sọrẹ, ìfé ti ilẹ̀ adúláwò, àti ìfé ti àgbáyé.

Bọọlu Alajus'awọn

Kí kópa nínù ere ìdárayá ti Bọọlu Alajus'awọn ni orílẹ̀ èdè wa - ọlọrẹ sọrẹ, ìfé ti ilẹ̀ adúláwò, àti ìfé ti àgbáyé.

Catch Them Young

Grassroots Talents
Discovery

Fill & Submit Form

Let D.R.Y Government Promote Your Talents

The Democratic Republic of the Yoruba Official Information Portal
The Democratic Republic of the Yoruba Official Information Portal
The Democratic Republic of the Yoruba Official Information Portal
The Democratic Republic of the Yoruba Official Information Portal
Sport Form (#25)

Àlàyé nípa rẹ àti ere ìdárayá tíó yàn láàyò

Jọ̀wọ́ bá wà fí fọọmù yí ránṣẹ́ lẹyin ti ẹ ba ti dáhùn àwọn ìbéèrè ti a bèrè fun. Àwọn ti o ni àmín ìràwọ̀ (*) ṣe pàtàki!

Àlàyé nípa ere ìdárayá tíó yàn láàyò