Àlàyé Pàtàkì Fún Òbí / Olùṣọ́:
i. Awọn aaye tí à sàmìnsí (*) ṣé pàtàki fún wa láti dáhùn.
ii. Ẹ fí orúkọ àwọn ọmọ (akẹ́kọ̀ọ́) yín silẹ ni ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ (Foomu kan, Akẹ́kọ̀ọ́ kan!).
iii. Lẹ́yìn tí ẹ bá ti fi form yii ránṣẹ́, ẹ maá ri atẹjade yii fún aridaju: “Thank you for taking time to fill this form. Your form has been submitted successfully.“
iv. Reload or refresh this page if the “submit Form” button is not responding.