General Data Collection Form

Àkíyèsí pàtàkì àti àlàyé nípa fọọmù yí:

👉 Fọwọsi fọọmu yi gẹgẹbi a ṣe gbé kalẹ; Awọn aaye tí à sàmìnsí (*) jẹ dandan fún wa!

👉 Ríi dájú pé Imeeli rẹ ń ṣíṣe. Àmọ́ tíò kò ba ní Imeeli, rí dájúdájú pé nọ́mbà Ẹ̀rọ Agbelewọ rẹ bára mú.

👉 Rí dájú pé òtítọ́ ni gbogbo òun ti o fi ránṣẹ́ ki o ma ba pàdánù àǹfààní náa.

👉 Pèsè fọto rẹ sílẹ̀ sórí ẹ̀rọ àgbéléwò rẹ tabi ẹ̀rọ ayára-bí-àṣà rẹ kí o to tẹsiwaju pẹ̀lú fọọmù yí; kí o sí rí dájú pé ko tóbi jú 1MB lọ. 👉 Àpẹẹrẹ fọto… Lo “.jpg” tàbí “.png”

The Democratic Republic of the Yoruba Official Information Portal

👉 Fún àlàyé lẹkunrẹrẹ, ẹ wo: https://youtu.be/byy2pFGz2-s

General Data Collection Form

Àwọn àlàyé t'ara ẹni

Jọ̀wọ́ bá wà fí fọọmù yí ránṣẹ́ lẹyin ti ẹ ba ti dáhùn àwọn ìbéèrè ti a bèrè fun. Àwọn ti o ni àmín ìràwọ̀ (*) ṣe pàtàki!


Àlàyé nípa Ìṣẹ́, ọgbọ́n ati ìmọ̀


Kàn síwa fún ìbéèrè lórí:

https://democraticrepublicoftheyoruba.com/contact/

Spread this information to your friends & family!

Shares