FORMS & GUIDELINES FOR YORUBA TUTORIAL CENTRE
Orúkọ Ati Ibugbe Olùdásílẹ̀ Ilé Idanilẹkọ YTC
Orúkọ Ìdílé àti Orúkọ Abisọ
Ibùgbé:
Nọmba Ẹrọ Agbelewọ:
Ímeèlì:
Ṣe Àlàyé Ní Ṣókí Nípa Àgbègbè (Surroundings) Ibi Tí Idanilẹkọ (YTC) Yìí Wà:
Ṣe Àlàyé Ní Ṣókí Nípa Ilè (Building) Ibi Tí Idanilẹkọ (YTC) Yìí Wà:
Kíni Àwọn Ètò Àti Ìlànà Fún Akẹkọ Láti Ríi Dájú Pe Èdè Yorùbá Rọrùn Fún Wọn Láti Kọ, Kà, Àti Láti le Sọ:
Kíni Àwọn Agbekalẹ Ètò Àti Ìlànà Fún Ìbojútó, Àyẹ̀wò, Ìdánwò Àwọn Akẹkọ Láti Ríi Dájú Pe Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá Ye Wọn Yéké-Yéké:
Njẹ O Níi Lọkàn Láti Gba Owó Fun Ètò Idanilẹkọ Yíì:
Eelo Ni Owó Fún Akẹkọ Kàn-kan:
Kajọ́dá Fún Ètò Idanilẹkọ YTC Rẹ ( Oye Ọjọ́ Nínú Ọ̀sẹ̀ Àti Oye Wákàtí Nínú Ọjọ́ Kan Fún Ikẹkọ):
WHAT ARE THE LESSON PLANS FOR THE YTC?
Kíni Àwọn Àmì Ìdánilójú Fún Ẹkọ Èdè Yorùbá To Péye, Ẹkọ To Gbòòrò Fún Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Rẹ:
Njẹ Ilè Àti Àgbègbè YTC Yìí Yíò Rọrùn Fún Akẹkọ Láì Sí Idiwọ Kánkan?:
Kíni Àwọn Ètò Àbò Àti Ìlànà Ìmọ́tótó Láti Ríi Dájú Pe Ilè Àti Àgbègbè YTC Yìí Yíò Rọrùn Fún Akẹkọ Láì Sí Idiwọ Kánkan?:
Èròngbà Wa Ni Pe Ki Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Mọ Èdè Yorùbá Ní Kíkọ, Kíkà, Àti Sísọ Láì Sí Idiwọ. Báwo Ní Èròngbà Wa Ṣe Leè Jọra?:
Dáhùn Àwọn Ìbéèrè Wọnyí Kí O Si Fi Àwọn Ìwé Èrí Fún Ìdánimọ̀ Rẹ Ránṣẹ́.
Submit YTC Form