Ìdàgbàs’okè Àwùjọ

Ìdàgbàs'okè Àwùjọ

Orílẹ̀-Èdè Yorùbá ní èròngbà à ti sọ ilẹ̀ Yorùbá di àwòkọ́’ṣe ní àgbáyé, pẹ̀lú oríṣiríṣi àwọn ohun am’ayédẹ’rùn fún ará ìlú L’ara ìwọ̀nyí ni ètò ilé-gbígbé fún gbogbo ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá.

ètò ilé-gbígbé fún gbogbo ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá

Àìrílégbe ti dópin nilẹ Yorùbá