Ètò Òkèèrè

Ètò Òkèèrè

Orílẹ̀-Èdè tí ó bá bu’yì fún wa ni a máa bu’yì fún. A kò ṣe ẹrú ẹnik’ẹni, bẹ́ẹ̀ ni a kò pa’dí àpò pọ̀ mọ́ ẹnik’ẹni l’ati ṣ’àbòsí ẹnik’ẹni.