Orílẹ̀-Èdè Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ Orílè-èdè Tuntun Olómìnira lati ọjọ Jimọ, ọjọ Kejìlá ti Oṣu Kẹrin (Igbe) ọdún 2024. Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ́ 17th ní Iwọ-oòrùn Áfíríkà, Orílẹ̀-èdè 55th ní Áfíríkà, ati Orílẹ̀-èdè Tuntun ni Àgbáyé. D.R.Y jáde kúrò, o sí farahàn ni àlàáfíà nipasẹ ìwé àdéhùn Àjọ Agbaye (UN) lorí ẹtọ ọmọ ènìyàn, àwọn ẹtọ ìpinnu-lọkan ara ẹnì fún idà dúró gẹgẹ bi orílè-èdè.
Akọkọ ìrù rẹ rèé tí orílẹ̀-èdè kàn jáde ní àlàáfíà láti di Orílẹ̀-èdè Olómìnira ní Áfíríkà! Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ ìṣẹ ọwọ Ọlọ́run Olódùmarè nípasẹ̀ ìyà wá Olólùfẹ́, Ọlọ́lá-jùlọ, Ọmọ-Aládé Modupẹọla Onitiri-Abiọla (MOA). Èyí jẹ ohun ti o dara lati gbọ ti gbogbo wa si ń ké ihò ayọ sí Ọlọ́run Ọba!
Let's build the cities we are proud of... Work has started in rebuilding our States to world standard.
Ibadan State of the Democratic Republic of the Yoruba Ìpínlẹ̀ Ibadan...
Explore Eko State – The Commercial Nerve Center of the Democratic...
Oyo Empire – The Empire of the Democratic Republic of the...
Ogun State of the Democratic Republic of the Yoruba Ogun State...
Ekiti State of the Democratic Republic of the Yoruba The Ekiti...
Osun State of the Democratic Republic of the Yorùbá Osun is...
Ondo State of the Democratic Republic of the Yorùbá The Ondo...
Orílẹ̀-Èdè Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ Orílè-èdè Tuntun Olómìnira lati ọjọ Jimọ, ọjọ Kejìlá ti Oṣu Kẹrin (Ìgbé) ọdún 2024. Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ́ 17th ní Iwọ-oòrùn Áfíríkà, Orílẹ̀-èdè 55th ní Áfíríkà, ati Orílẹ̀-èdè Tuntun ni Àgbáyé. D.R.Y jáde kúrò, o sí farahàn ni àlàáfíà nipasẹ ìwé àdéhùn Àjọ Àgbáyé (UN) lorí ẹtọ ọmọ ènìyàn, àwọn ẹtọ ìpinnu-lọkan ara ẹnì fún idà dúró gẹgẹ bi orílè-èdè.
© Copyright 2024 Nípasẹ̀ Alákóso Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá